O. Daf 115:14-16

O. Daf 115:14-16 YBCV

Oluwa yio mu nyin bisi i siwaju ati siwaju, ẹnyin ati awọn ọmọ nyin. Ẹnyin li ẹni-ibukún Oluwa, ti o da ọrun on aiye. Ọrun ani ọrun ni ti Oluwa; ṣugbọn aiye li o fi fun awọn ọmọ enia.