O. Daf 114:1-3

O. Daf 114:1-3 YBCV

NIGBATI Israeli jade kuro ni Egipti, ti ara-ile Jakobu kuro ninu àjeji ède enia; Juda di ibi mimọ́ rẹ̀, Israeli di ijọba rẹ̀. Okun ri i, o si sá: Jordani pada sẹhin.