Pẹlupẹlu o pè ìyan wá si ilẹ na: o ṣẹ́ gbogbo ọpá onjẹ. O rán ọkunrin kan lọ siwaju wọn; ani Josefu ti a tà li ẹrú: Ẹsẹ ẹniti nwọn fi ṣẹkẹṣẹkẹ pa lara: a dè e ninu irin: Titi igba ti ọ̀rọ rẹ̀ de: ọ̀rọ Oluwa dan a wò. Ọba ranṣẹ, nwọn si tú u silẹ; ani ijoye awọn enia, o si jọwọ rẹ̀ lọwọ lọ. O fi jẹ oluwa ile rẹ̀, ati ijoye gbogbo ini rẹ̀. Lati ma ṣe akoso awọn ọmọ-alade rẹ̀ nipa ifẹ rẹ̀; ati lati ma kọ́ awọn igbimọ rẹ̀ li ọgbọ́n.
Kà O. Daf 105
Feti si O. Daf 105
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: O. Daf 105:16-22
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò