O. Daf 102:2-3

O. Daf 102:2-3 YBCV

Máṣe pa oju rẹ mọ́ kuro lara mi li ọjọ ti emi wà ninu ipọnju; dẹ eti rẹ si mi: li ọjọ ti mo ba pè, da mi lohùn-lọgan. Nitori ti ọjọ mi run bi ẹ̃fin, egungun mi si jona bi àro.