O. Daf 102:11-12

O. Daf 102:11-12 YBCV

Ọjọ mi dabi ojiji ti o nfà sẹhin; emi si nrọ bi koriko. Ṣugbọn iwọ, Oluwa, ni yio duro lailai; ati iranti rẹ lati iran dé iran.