O. Daf 100:1-2

O. Daf 100:1-2 YBCV

Ẹ ho iho ayọ̀ si Oluwa, ẹnyin ilẹ gbogbo. Ẹ fi ayọ̀ sìn Oluwa: ẹ wá ti ẹnyin ti orin si iwaju rẹ̀.