Owe 6:6-8

Owe 6:6-8 YBCV

Tọ ẽrùn lọ, iwọ ọlẹ: kiyesi iṣe rẹ̀ ki iwọ ki o si gbọ́n: Ti kò ni onidajọ, alabojuto, tabi alakoso. Ti npese onjẹ rẹ̀ ni igba-ẹ̀run, ti o si nkó onjẹ rẹ̀ jọ ni ìgba ikore.