Owe 31:9

Owe 31:9 YBCV

Yà ẹnu rẹ, fi ododo ṣe idajọ, ki o si gbèja talaka ati alaini.