Owe 31:8-9

Owe 31:8-9 YBCV

Yà ẹnu rẹ fun ayadi, ninu ọ̀ran gbogbo ẹniti iṣe ọmọ iparun. Yà ẹnu rẹ, fi ododo ṣe idajọ, ki o si gbèja talaka ati alaini.