Owe 31:16

Owe 31:16 YBCV

O kiyesi oko, o si mu u: ère ọwọ rẹ̀ li o fi gbin ọgbà-ajara.