Owe 31:10-12

Owe 31:10-12 YBCV

Tani yio ri obinrin oniwà rere? nitoriti iye rẹ̀ kọja iyùn. Aiya ọkọ rẹ̀ gbẹkẹle e laibẹ̀ru, bẹ̃ni on kì yio ṣe alaini ère iṣẹ. Rere li obinrin na yio ma ṣe fun u, kì iṣe buburu li ọjọ aiye rẹ̀ gbogbo.