Owe 27:15-16

Owe 27:15-16 YBCV

Ọṣọrọ-òjo li ọjọ òjo, ati onija obinrin, bakanna ni. Ẹnikẹni ti o pa a mọ́, o pa ẹfũfu mọ́, ororo ọwọ-ọtún rẹ̀ yio si fihàn.