Owe 25:6-7

Owe 25:6-7 YBCV

Máṣe ṣefefe niwaju ọba, má si ṣe duro ni ipò awọn enia nla. Nitoripe, o san ki a wi fun ọ pe, wá soke nihin, jù ki a fà ọ tì sẹhin niwaju ọmọ-alade ti oju rẹ ti ri.