Owe 23:17-18

Owe 23:17-18 YBCV

Máṣe jẹ ki aiya rẹ ki o ṣe ilara si awọn ẹ̀lẹṣẹ, ṣugbọn ki iwọ ki o wà ni ibẹ̀ru Oluwa, li ọjọ gbogbo. Nitoripe ikẹhin mbẹ nitõtọ; ireti rẹ kì yio si ke kuro.