Owe 14:26-27

Owe 14:26-27 YBCV

Ni ibẹ̀ru Oluwa ni igbẹkẹle ti o lagbara: yio si jẹ ibi àbo fun awọn ọmọ rẹ̀. Ibẹ̀ru Oluwa li orisun ìye, lati kuro ninu ikẹkùn ikú.