Filp 4:23

Filp 4:23 YBCV

Ore-ọfẹ Jesu Kristi Oluwa wa, ki o wà pẹlu ẹmi nyin. Amin. A kọ ọ si awọn ara Filippi lati Romu lọ lati ọwọ́ Epafroditu.