Num 31:1-2

Num 31:1-2 YBCV

OLUWA si sọ fun Mose pe, Gbẹsan awọn ọmọ Israeli lara awọn ara Midiani: lẹhin eyinì ni a o kó ọ jọ pẹlu awọn enia rẹ.