Num 23:19-20

Num 23:19-20 YBCV

Ọlọrun ki iṣe enia ti yio fi ṣeké; bẹ̃ni ki iṣe ọmọ enia ti yio fi ronupiwada: a ma wi, ki o má si ṣe bi? tabi a ma sọ̀rọ ki o má mu u ṣẹ? Kiyesi i, emi gbà aṣẹ ati sure: on si ti sure, emi kò si le yì i.