Neh 10:1-27

Neh 10:1-27 YBCV

AWỌN ti o fi èdidi di i ni Nehemiah, bãlẹ, ọmọ Hakaliah, ati Sidkijah. Seraiah, Asariah, Jeremiah, Paṣuri, Amariah, Malkijah, Hattuṣi, Ṣebaniah, Malluki, Harimu, Meremoti, Obadiah, Danieli, Ginnetoni, Baruki, Meṣullamu, Abijah, Mijamini, Maaṣiah, Bilgai, Ṣemaiah: alufa li awọn wọnyi. Ati awọn ọmọ Lefi: ati Jeṣua ọmọ Asaniah, Binnui, ọkan ninu awọn ọmọ Henadadi, Kadmieli; Ati awọn arakunrin wọn, Ṣebaniah, Hodijah, Kelita, Pelaiah, Hanani, Mika, Rehobu, Haṣabiah, Sakkuri, Ṣerebiah, Ṣebaniah, Hodijah, Bani, Beninu. Awọn olori awọn enia; Paroṣi, Pahati-moabu, Elamu, Sattu, Bani. Bunni, Asgadi, Bebai, Adonijah, Bigfai, Adini, Ateri, Hiskijah, Assuri, Hodijah, Haṣumu, Besai, Harifi, Anatoti, Nebai, Magpiaṣi, Meṣullamu, Hasiri, Meṣesabeeli, Sadoku, Jaddua, Pelatiah, Hanani, Anaiah, Hoṣea, Hananiah, Haṣubu, Halloheṣi, Pileha, Ṣobeki, Rehumu, Hasabna, Maaseiah, Ati Ahijah, Hanani, Anani, Malluku, Harimu, Baana.