Mak 6:46-47

Mak 6:46-47 YBCV

Nigbati o si rán wọn lọ tan, o gùn ori òke lọ igbadura. Nigbati alẹ si lẹ, ọkọ̀ si wà larin okun, on nikan si wà ni ilẹ.

Àwọn fídíò fún Mak 6:46-47