Lọgan ni isun ẹ̀jẹ rẹ̀ si ti gbẹ; on si mọ̀ lara rẹ̀ pe, a mu on larada ninu arun na. Lọgan Jesu si ti mọ̀ ninu ara rẹ̀ pe, aṣẹ ti ara on jade, o yipada larin ọpọ enia, o si wipe, Tali o fi ọwọ́ kàn mi li aṣọ? Awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ wi fun u pe, Iwọ ri bi ijọ enia ti nhá ọ li àye, iwọ si nwipe, Tali o fi ọwọ́ tọ́ mi? O si wò yiká lati ri ẹniti o ṣe nkan yi. Ṣugbọn obinrin na ni ibẹ̀ru ati iwarìri, bi o ti mọ̀ ohun ti a ṣe lara on, o wá, o si wolẹ niwaju rẹ̀, o si sọ gbogbo otitọ fun u. O si wi fun u pe, Ọmọbinrin, igbagbọ́ rẹ mu ọ larada; mã lọ li alafia, ki iwọ ki o si sàn ninu arun rẹ.
Kà Mak 5
Feti si Mak 5
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Mak 5:29-34
7 Awọn ọjọ
Ninu ori ti o yẹ, onkọwe ti Ihinrere Luku ṣakọsilẹ ẹkọ Jesu lori igbesi aye adura ti onigbagbọ. Ẹ̀kọ́ yìí ni wọ́n fi ń kọ́ni lọ́nà àkàwé. Idi ti owe naa ni lati kọ pe awọn onigbagbọ ni ipinnu lati gbadura ni gbogbo igbesi aye wọn ati pe wọn ko duro.
10 Days
Depression. Anxiety. Triggers and traumatic events take a mental, emotional, and spiritual toll on us. During these times seeking God seems difficult and redundant. The plan, "Seek God Through It" aims to encourage and teach you how to be proactive in the presence of God so you may experience the peace of God, no matter your situation.
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò