Mak 10:7-8

Mak 10:7-8 YBCV

Nitori eyi li ọkunrin yio ṣe fi baba ati iya rẹ̀ silẹ ti yio si faramọ aya rẹ̀; Awọn mejeji a si di ara kan: nitorina nwọn kì iṣe meji mọ́, bikoṣe ara kan.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ