Mak 1:35-37

Mak 1:35-37 YBCV

O si dide li owurọ̀ ki ilẹ to mọ́, o si jade lọ si ibi iju kan, nibẹ li o si ngbadura. Simoni ati awọn ti o wà pẹlu rẹ̀ si nwá a. Nigbati nwọn si ri i, nwọn wi fun u pe, Gbogbo enia nwá ọ.

Àwọn fídíò fún Mak 1:35-37