Mik 3:1-2

Mik 3:1-2 YBCV

EMI si wipe, Gbọ́, emi bẹ̀ nyin, ẹnyin olori ni Jakobu, ati ẹnyin alakoso ile Israeli; ti nyin kì iṣe lati mọ̀ idajọ bi? Ẹnyin ti o korira ire, ti ẹ si fẹ ibi; ti ẹ já awọ-ara wọn kuro lara wọn, ati ẹran-ara wọn kuro li egungun wọn