Mat 6:4

Mat 6:4 YBCV

Ki itọrẹ ãnu rẹ ki o le wà ni ìkọkọ; Baba rẹ ti o si riran ni ìkọkọ, on tikararẹ̀ yio san a fun ọ ni gbangba.

Àwọn fídíò fún Mat 6:4