Mat 6:31

Mat 6:31 YBCV

Nitorina ẹ maṣe ṣe aniyan, wipe, Kili a o jẹ? tabi, Kili a o mu? tabi, aṣọ wo li a o fi wọ̀ wa?

Àwọn fídíò fún Mat 6:31