Mat 6:10-13

Mat 6:10-13 YBCV

Ki ijọba rẹ de; Ifẹ tirẹ ni ki a ṣe, bi ti ọrun, bẹ̃ni li aiye. Fun wa li onjẹ õjọ wa loni. Dari gbese wa jì wa, bi awa ti ndarijì awọn onigbese wa. Má si fà wa sinu idẹwò, ṣugbọn gbà wa lọwọ bilisi. Nitori ijọba ni tirẹ, ati agbara, ati ogo, lailai. Amin.

Àwọn fídíò fún Mat 6:10-13

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Mat 6:10-13

Mat 6:10-13 - Ki ijọba rẹ de; Ifẹ tirẹ ni ki a ṣe, bi ti ọrun, bẹ̃ni li aiye.
Fun wa li onjẹ õjọ wa loni.
Dari gbese wa jì wa, bi awa ti ndarijì awọn onigbese wa.
Má si fà wa sinu idẹwò, ṣugbọn gbà wa lọwọ bilisi. Nitori ijọba ni tirẹ, ati agbara, ati ogo, lailai. Amin.Mat 6:10-13 - Ki ijọba rẹ de; Ifẹ tirẹ ni ki a ṣe, bi ti ọrun, bẹ̃ni li aiye.
Fun wa li onjẹ õjọ wa loni.
Dari gbese wa jì wa, bi awa ti ndarijì awọn onigbese wa.
Má si fà wa sinu idẹwò, ṣugbọn gbà wa lọwọ bilisi. Nitori ijọba ni tirẹ, ati agbara, ati ogo, lailai. Amin.