Mat 5:46-48

Mat 5:46-48 YBCV

Nitori bi ẹnyin ba fẹ awọn ti o fẹ nyin, ọpẹ́ kili ẹnyin ni? bẹ̃ gẹgẹ ki awọn agbowode nṣe? Bi ẹnyin ba si nkí kìki awọn arakunrin nyin, kili ẹ ṣe jù awọn ẹlomiran lọ? bẹ̃ gẹgẹ ki awọn agbowode nṣe? Nitorina ki ẹnyin ki o pé, bi Baba nyin ti mbẹ li ọrun ti pé.

Àwọn fídíò fún Mat 5:46-48