Mat 5:41-42

Mat 5:41-42 YBCV

Ẹnikẹni ti yio ba fi agbara mu ọ lọ si maili kan, bá a de meji. Fifun ẹniti o bère lọwọ rẹ; ati lọdọ ẹniti o nfẹ win lọwọ rẹ, máṣe mu oju kuro.

Àwọn fídíò fún Mat 5:41-42