Mat 5:13-14

Mat 5:13-14 YBCV

Ẹnyin ni iyọ̀ aiye: ṣugbọn bi iyọ̀ ba di obu, kini a o fi mu u dùn? kò nilari mọ́, bikoṣepe a dà a nù, ki o si di itẹmọlẹ li atẹlẹsẹ enia. Ẹnyin ni imọlẹ aiye. Ilu ti a tẹ̀do lori òke ko le farasin.

Àwọn fídíò fún Mat 5:13-14

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Mat 5:13-14

Mat 5:13-14 - Ẹnyin ni iyọ̀ aiye: ṣugbọn bi iyọ̀ ba di obu, kini a o fi mu u dùn? kò nilari mọ́, bikoṣepe a dà a nù, ki o si di itẹmọlẹ li atẹlẹsẹ enia.
Ẹnyin ni imọlẹ aiye. Ilu ti a tẹ̀do lori òke ko le farasin.Mat 5:13-14 - Ẹnyin ni iyọ̀ aiye: ṣugbọn bi iyọ̀ ba di obu, kini a o fi mu u dùn? kò nilari mọ́, bikoṣepe a dà a nù, ki o si di itẹmọlẹ li atẹlẹsẹ enia.

Ẹnyin ni imọlẹ aiye. Ilu ti a tẹ̀do lori òke ko le farasin.