Mat 4:18-20

Mat 4:18-20 YBCV

Jesu nrin leti okun Galili, o ri awọn arakunrin meji, Simoni, ẹniti a npè ni Peteru, ati Anderu arakunrin rẹ̀, nwọn nsọ àwọn sinu okun: nitori nwọn jẹ apẹja. O si wi fun wọn pe, Ẹ mã tọ̀ mi lẹhin, emi ó si sọ nyin di apẹja enia. Nwọn si fi àwọn silẹ lojukanna, nwọn sì tọ̀ ọ lẹhin.

Àwọn fídíò fún Mat 4:18-20