Nigbati o si jade kuro ni Nasareti, o wá ijoko ni Kapernaumu, eyi ti o mbẹ leti okun li ẹkùn Sebuloni ati Neftalimu: Ki eyi ti a wi lati ẹnu woli Isaiah wá le ṣẹ, pe
Kà Mat 4
Feti si Mat 4
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Mat 4:13-14
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò