Mat 26:3-4

Mat 26:3-4 YBCV

Nigbana li awọn olori alufa, awọn akọwe, ati awọn àgba awọn enia pejọ li ãfin olori alufa, ẹniti a npè ni Kaíafa, Nwọn si jọ gbìmọ lati fi ẹ̀tan mu Jesu, ki nwọn si pa a.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ