Mat 24:36

Mat 24:36 YBCV

Ṣugbọn niti ọjọ ati wakati na, kò si ẹnikan ti o mọ̀ ọ, awọn angẹli ọrun kò tilẹ mọ̀ ọ, bikoṣe Baba mi nikanṣoṣo.

Àwọn fídíò fún Mat 24:36