Mat 21:18-19

Mat 21:18-19 YBCV

Nigbati o di owurọ̀, bi o ti npada bọ̀ si Jerusalemu, ebi npa a. Nigbati o ri igi ọ̀pọtọ li ọ̀na, o lọ sibẹ̀, kò si ri ohun kan lori rẹ̀, bikoṣe kìki ewé, o si wi fun u pe, Ki eso ki o má so lori rẹ lati oni lọ titi lailai. Lojukanna igi ọpọtọ na gbẹ.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ