Mat 21:10-11

Mat 21:10-11 YBCV

Nigbati o de Jerusalemu, gbogbo ilu mì titi, wipe, Tani yi? Ijọ enia si wipe, Eyi ni Jesu wolĩ, lati Nasareti ti Galili.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ