Mat 20:32-34

Mat 20:32-34 YBCV

Jesu si dẹsẹ duro, o pè wọn, o si wipe, Kili ẹnyin nfẹ ki emi ki o ṣe fun nyin? Nwọn wi fun u pe, Oluwa, ki oju wa ki o le là. Bẹ̃ni Jesu ṣãnu fun wọn, o si fi ọwọ́ tọ́ wọn li oju: lọgan oju wọn si là, nwọn si tọ̀ ọ lẹhin.

Àwọn fídíò fún Mat 20:32-34