Mat 20:32-33

Mat 20:32-33 YBCV

Jesu si dẹsẹ duro, o pè wọn, o si wipe, Kili ẹnyin nfẹ ki emi ki o ṣe fun nyin? Nwọn wi fun u pe, Oluwa, ki oju wa ki o le là.

Àwọn fídíò fún Mat 20:32-33