Mat 17:22-23

Mat 17:22-23 YBCV

Nigbati nwọn mbẹ ni Galili, Jesu wi fun wọn pe, A o fi Ọmọ-enia le awọn enia lọwọ: Nwọn o si pa a, ni ijọ kẹta yio si jinde. Inu wọn si bajẹ gidigidi.

Àwọn fídíò fún Mat 17:22-23