Mat 14:31-33

Mat 14:31-33 YBCV

Lojukanna Jesu si nà ọwọ́ rẹ̀, o dì i mu, o si wi fun u pe, Iwọ onigbagbọ́ kekere, ẽṣe ti iwọ fi nṣiyemeji? Nigbati nwọn si bọ́ sinu ọkọ̀, afẹfẹ dá. Nigbana li awọn ti mbẹ ninu ọkọ̀ wá, nwọn si fi ori balẹ fun u, wipe, Lõtọ Ọmọ Ọlọrun ni iwọ iṣe.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ