Mat 13:45-46

Mat 13:45-46 YBCV

Ati pẹlu, ijọba ọrun si dabi ọkunrin oniṣowo kan, ti nwá perli ti o dara: Nigbati o ri perli olowo iyebiye kan, o lọ, o si tà gbogbo nkan ti o ni, o si rà á.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ