O si wi fun gbogbo wọn pe, Bi ẹnikan ba nfẹ lati mã tọ̀ mi lẹhin, ki o sẹ́ ara rẹ̀, ki o si gbé agbelebu rẹ̀ ni ijọ gbogbo, ki o si mã tọ̀ mi lẹhin. Nitori ẹnikẹni ti o ba fẹ gbà ẹmí rẹ̀ là, yio sọ ọ nù: ṣugbọn ẹnikẹni ti o ba sọ ẹmí rẹ̀ nù nitori mi, on na ni yio si gbà a là. Nitoripe ère kini fun enia, bi o jère gbogbo aiye, ti o si sọ ara rẹ̀ nù, tabi ki o fi ara rẹ̀ ṣòfò.
Kà Luk 9
Feti si Luk 9
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Luk 9:23-25
6 Days
I believed in a lie for years. This lie is all too common in Christian circles. I believed in a secular-sacred dichotomy. And it held me back. Join me to explore how God wants to supernaturally empower us to bring Heaven to Earth and to succeed in business and life. We have more opportunities to impact the world than most “full-time ministers," and this Bible plan will show you how!
7 Days
Explore your purpose as a follower of Jesus: to love God and love others. Over seven days, we will unpack the themes of personal worship, transformation, compassion, service, and justice. Each session starts with a prayer to help you focus on the day’s theme, a passage or two from scripture, a thought from a theological perspective, and ways to apply and respond to the reading.
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò