Luk 9:1-2

Luk 9:1-2 YBCV

O si pè awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ mejila jọ, o si fun wọn li agbara on aṣẹ lori awọn ẹmi èṣu gbogbo, ati lati wò arùn sàn. O si rán wọn lọ iwasu ijọba Ọlọrun, ati lati mu awọn olokunrun larada.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ