Luk 6:41

Luk 6:41 YBCV

Ẽṣe ti iwọ si nwò ẹrún igi ti mbẹ li oju arakunrin rẹ, ṣugbọn iwọ kò kiyesi ìti igi ti mbẹ li oju ara rẹ?

Àwọn fídíò fún Luk 6:41