Luk 5:31-32

Luk 5:31-32 YBCV

Jesu dahùn o si wi fun wọn pe, Awọn ti ara wọn dá kò wá oniṣegun, bikoṣe awọn ti ara wọn kò da. Emi kò wá ipè awọn olododo, bikoṣe awọn ẹlẹṣẹ si ironupiwada.

Àwọn fídíò fún Luk 5:31-32