Luk 5:27-29

Luk 5:27-29 YBCV

Lẹhin nkan wọnyi o jade lọ, o si ri agbowode kan ti a npè ni Lefi, o joko ni bode: o si wi fun u pe, Mã tọ̀ mi lẹhin. O si fi gbogbo nkan silẹ, o dide, o si ntọ̀ ọ lẹhin. Lefi si se àse nla fun u ni ile rẹ̀: ọ̀pọ ijọ awọn agbowode, ati awọn ẹlomiran mbẹ nibẹ̀ ti nwọn ba wọn joko.

Àwọn fídíò fún Luk 5:27-29