Luk 22:29-30

Luk 22:29-30 YBCV

Mo si yàn ijọba fun nyin, gẹgẹ bi Baba mi ti yàn fun mi; Ki ẹnyin ki o le mã jẹ, ki ẹnyin ki o si le mã mu lori tabili mi ni ijọba mi, ki ẹnyin ki o le joko lori itẹ́, ati ki ẹnyin ki o le mã ṣe idajọ fun awọn ẹ̀ya Israeli mejila.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ