Luk 21:13-15

Luk 21:13-15 YBCV

Yio si pada di ẹrí fun nyin. Nitorina ẹ pinnu rẹ̀ li ọkàn nyin pe ẹ kì yio ronu ṣaju, bi ẹ o ti dahun. Nitoriti emi ó fun nyin li ẹnu ati ọgbọ́n, ti gbogbo awọn ọtá nyin kì yio le sọrọ-òdi si, ti nwọn kì yio si le kò loju.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ