Luk 20:45-47

Luk 20:45-47 YBCV

O si wi fun awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ li etí gbogbo enia pe, Ẹ mã kiyesara lọdọ awọn akọwe, ti nwọn fẹ lati mã rìn li aṣọ gigùn, ti nwọn si fẹ ikí-ni li ọjà, ati ibujoko ọlá ninu sinagogu, ati ipò ọla ni ibi àse; Awọn ti o jẹ ile awọn opó run, ti nwọn si ngbadura gìgun fun aṣehàn: awọn wọnyi na ni yio jẹbi pọ̀ju.

Àwọn fídíò fún Luk 20:45-47