Luk 19:9-10

Luk 19:9-10 YBCV

Jesu si wi fun u pe, Loni ni igbala wọ̀ ile yi, niwọnbi on pẹlu ti jẹ ọmọ Abrahamu. Nitori Ọmọ-enia de lati wá awọn ti o nù kiri, ati lati gbà wọn là.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ